Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọmba 17:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. OLUWA sọ fún Mose pé,

2. “Gba ọ̀pá mejila láti ọwọ́ àwọn ọmọ Israẹli, ọ̀pá kọ̀ọ̀kan láti ọwọ́ olórí ẹ̀yà kọ̀ọ̀kan, kí o sì kọ orúkọ olukuluku sí ara ọ̀pá tirẹ̀.

Ka pipe ipin Nọmba 17