Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọmba 16:14 BIBELI MIMỌ (BM)

O kò tíì kó wa dé ilẹ̀ tí ó lọ́ràá tí ó kún fún wàrà ati oyin, tabi kí o fún wa ní ọgbà àjàrà ati oko. Ṣé o fẹ́ fi júújúú bo àwọn eniyan wọnyi lójú ni, a kò ní dá ọ lóhùn.”

Ka pipe ipin Nọmba 16

Wo Nọmba 16:14 ni o tọ