Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọmba 16:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣé ẹ kò mọ̀ pé OLUWA ni ìwọ ati àwọn ẹlẹgbẹ́ rẹ ń ṣọ̀tẹ̀ sí, nígbà tí ẹ̀ ń fi ẹ̀sùn kan Aaroni? Ta ni Aaroni tí ẹ̀yin ń fi ẹ̀sùn kàn?”

Ka pipe ipin Nọmba 16

Wo Nọmba 16:11 ni o tọ