Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọmba 15:38 BIBELI MIMỌ (BM)

“Pàṣẹ fún àwọn ọmọ Israẹli kí wọ́n ṣe oko jọnwọnjọnwọn sí etí aṣọ wọn ní ìrandíran wọn; kí wọ́n sì ta okùn aláwọ̀ aró mọ oko jọnwọnjọnwọn kọ̀ọ̀kan.

Ka pipe ipin Nọmba 15

Wo Nọmba 15:38 ni o tọ