Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọmba 15:30 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ṣugbọn ẹnikẹ́ni tí ó bá mọ̀ọ́nmọ̀ ṣẹ̀, kò náání OLUWA, ìbáà ṣe ọmọ Israẹli tabi àjèjì tí ń gbé láàrin wọn, a óo yọ olúwarẹ̀ kúrò láàrin àwọn eniyan rẹ̀;

Ka pipe ipin Nọmba 15

Wo Nọmba 15:30 ni o tọ