Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọmba 15:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìlànà kan náà ni yóo wà fún gbogbo ìjọ eniyan Israẹli ati àwọn àjèjì tí wọ́n wà láàrin yín. Ìlànà yìí yóo wà títí lae ní ìrandíran yín. Bí ẹ ti rí níwájú OLUWA, bẹ́ẹ̀ náà ni àjèjì tí ó wà láàrin yín rí.

Ka pipe ipin Nọmba 15

Wo Nọmba 15:15 ni o tọ