Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọmba 12:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọn ń wí pé, “Ṣé Mose nìkan ni OLUWA ti lò láti bá eniyan sọ̀rọ̀ ni? Ṣé kò ti lo àwa náà rí?” OLUWA sì gbọ́ ọ̀rọ̀ tí wọn ń sọ.

Ka pipe ipin Nọmba 12

Wo Nọmba 12:2 ni o tọ