Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọmba 12:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ọ̀wọ̀n ìkùukùu tí ó wà ní ẹnu ọ̀nà Àgọ́ Àjọ ti gbéra sókè ni ẹ̀tẹ̀ bo Miriamu, ó sì funfun bí ẹ̀gbọ̀n òwú. Nígbà tí Aaroni wo Miriamu ó ri wí pé ó ti di adẹ́tẹ̀.

Ka pipe ipin Nọmba 12

Wo Nọmba 12:10 ni o tọ