Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemaya 9:8 BIBELI MIMỌ (BM)

O rí i pé ó ṣe olóòótọ́ sí ọ, O sì bá a dá majẹmu láti fún àwọn ìran rẹ̀ ní ilẹ̀ àwọn ará Kenaani ati ti àwọn ará Hiti, ti àwọn ará Amori, ti àwọn ará Perisi, ti àwọn ará Jebusi ati ti àwọn ará Girigaṣi, o sì ti mú ìlérí náà ṣẹ nítorí pé olódodo ni ọ́.

Ka pipe ipin Nehemaya 9

Wo Nehemaya 9:8 ni o tọ