Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemaya 9:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọpọlọpọ ọdún ni o fi mú sùúrù pẹlu wọ́n, tí o sì ń kìlọ̀ fún wọn nípasẹ̀ Ẹ̀mí rẹ, láti ẹnu àwọn wolii rẹ, sibẹ wọn kò fetí sílẹ̀. Nítorí náà ni o ṣe jẹ́ kí àwọn tí ń gbé ilẹ̀ náà ṣẹgun wọn.

Ka pipe ipin Nehemaya 9

Wo Nehemaya 9:30 ni o tọ