Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemaya 8:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹsira, alufaa, gbé ìwé òfin náà jáde siwaju àpéjọ náà, tọkunrin tobinrin, gbogbo àwọn tí wọ́n lè gbọ́ kíkà òfin náà kí ó sì yé wọn ni wọ́n péjọ, ní ọjọ́ kinni oṣù keje.

Ka pipe ipin Nehemaya 8

Wo Nehemaya 8:2 ni o tọ