Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemaya 7:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Orúkọ àwọn eniyan agbègbè náà, tí wọ́n pada ninu àwọn tí Nebukadinesari ọba Babiloni kó lọ sí ìgbèkùn, tí wọ́n pada sí Jerusalẹmu ati Juda, tí olukuluku wọn sì pada sí ìlú rẹ̀ nìwọ̀nyí.

Ka pipe ipin Nehemaya 7

Wo Nehemaya 7:6 ni o tọ