Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemaya 7:28-30 BIBELI MIMỌ (BM)

28. Àwọn ará Beti Asimafeti jẹ́ mejilelogoji.

29. Àwọn ará Kiriati Jearimu ati Kefira ati Beeroti jẹ́ ọtadinlẹgbẹrin ó lé mẹta (743).

30. Àwọn ará Rama ati Geba jẹ́ ẹgbẹta lé mọkanlelogun (621).

Ka pipe ipin Nehemaya 7