Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemaya 7:2 BIBELI MIMỌ (BM)

mo yan arakunrin mi, Hanani, ati Hananaya, gomina ilé ìṣọ́, láti máa ṣe àkóso Jerusalẹmu, nítorí pé Hananaya jẹ́ olóòótọ́ ó sì bẹ̀rù Ọlọrun ju ọpọlọpọ àwọn yòókù lọ.

Ka pipe ipin Nehemaya 7

Wo Nehemaya 7:2 ni o tọ