Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemaya 7:12-14 BIBELI MIMỌ (BM)

12. Àwọn ọmọ Elamu jẹ́ ẹgbẹfa ó lé mẹrinlelaadọta (1,254).

13. Àwọn ọmọ Satu jẹ́ ojilelẹgbẹrin ó lé marun-un (845).

14. Àwọn ọmọ Sakai jẹ́ ojidinlẹgbẹrin (760).

Ka pipe ipin Nehemaya 7