Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemaya 6:7 BIBELI MIMỌ (BM)

ati pé o tilẹ̀ ti yan àwọn wolii láti máa kéde nípa rẹ ní Jerusalẹmu pé, ‘Ọba kan wà ní Juda.’ Ó pẹ́ ni, ó yá ni, ọba yóo gbọ́ ìròyìn yìí. Nítorí náà, wá kí á jọ jíròrò nípa ọ̀rọ̀ náà.”

Ka pipe ipin Nehemaya 6

Wo Nehemaya 6:7 ni o tọ