Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemaya 6:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí àwọn ọ̀tá wa, ní gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè tí ó yí wa ká gbọ́ nípa rẹ̀, ẹ̀rù bà wọ́n, ìtìjú sì mú wọn, nítorí wọ́n mọ̀ pé nípa ìrànlọ́wọ́ Ọlọrun ni iṣẹ́ náà fi ṣeéṣe.

Ka pipe ipin Nehemaya 6

Wo Nehemaya 6:16 ni o tọ