Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemaya 6:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n bẹ̀ ẹ́ lọ́wẹ̀ kí ó lè dẹ́rù bà mí, kí n lè ṣe bí ó ti wí, kí n dẹ́ṣẹ̀, kí wọ́n lè bà mí ní orúkọ jẹ́, kí wọ́n wá kẹ́gàn mi.

Ka pipe ipin Nehemaya 6

Wo Nehemaya 6:13 ni o tọ