Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemaya 5:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Siwaju sí i, láti ìgbà tí a ti yàn mí sí ipò gomina ní ilẹ̀ Juda, láti ogun ọdún tí Atasasesi ti jọba sí ọdún kejilelọgbọn, èmi ati arakunrin mi kò jẹ oúnjẹ tí wọ́n yà sọ́tọ̀ fún wa gẹ́gẹ́ bíi gomina.

Ka pipe ipin Nehemaya 5

Wo Nehemaya 5:14 ni o tọ