Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemaya 4:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà mo fi àwọn eniyan ṣọ́ gbogbo ibi tí odi ìlú bá ti gba ibi tí ilẹ̀ ti dà gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́, mo yan olukuluku ní ìdílé ìdílé, wọ́n ń ṣọ́ odi ní agbègbè wọn pẹlu idà, ọ̀kọ̀, ati ọrun wọn.

Ka pipe ipin Nehemaya 4

Wo Nehemaya 4:13 ni o tọ