Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemaya 4:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọ̀tá wa sì wí pé, “Wọn kò ní mọ ohun tí ń ṣẹlẹ̀, bẹ́ẹ̀ ni wọn kò ní rí wa títí tí a óo fi dé ọ̀dọ̀ wọn, tí a óo pa wọ́n, tí iṣẹ́ náà yóo sì dúró.”

Ka pipe ipin Nehemaya 4

Wo Nehemaya 4:11 ni o tọ