Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemaya 3:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn wọn ni Meremoti, ọmọ Uraya, ọmọ Hakosi ṣe àtúnṣe abala ọ̀dọ̀ wọn.Lẹ́yìn wọn, Meṣulamu ọmọ Berekaya, ọmọ Meṣesabeli náà ṣe àtúnṣe abala ọ̀dọ̀ wọn.Lẹ́yìn wọn ni Sadoku, ọmọ Baana náà ṣe àtúnṣe abala tiwọn.

Ka pipe ipin Nehemaya 3

Wo Nehemaya 3:4 ni o tọ