Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemaya 3:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn rẹ̀ Malikija, ọ̀kan ninu àwọn alágbẹ̀dẹ wúrà, ṣe àtúnṣe títí dé ilé àwọn iranṣẹ tẹmpili ati ilé àwọn oníṣòwò, níbi tí ó kọjú sí Ẹnu Ọ̀nà Mifikadi, ati títí dé yàrá òkè orígun odi.

Ka pipe ipin Nehemaya 3

Wo Nehemaya 3:31 ni o tọ