Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemaya 3:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn wọn, Sadoku, ọmọ Imeri, ṣe àtúnṣe ibi tí ó kọjú sí ilé tirẹ̀.Lẹ́yìn rẹ̀ ni Ṣemaaya, ọmọ Ṣekanaya, olùṣọ́ ẹnu ọ̀nà ìhà ìlà oòrùn, ṣe àtúnṣe ọ̀dọ̀ tirẹ̀.

Ka pipe ipin Nehemaya 3

Wo Nehemaya 3:29 ni o tọ