Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemaya 3:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣalumu ọmọ Kolihose, aláṣẹ agbègbè Misipa tún Ẹnubodè Orísun ṣe, ó tún un kọ́, ó bò ó, ó sì ṣe àwọn ìlẹ̀kùn rẹ̀ ati ọ̀pá ìdábùú rẹ̀, ó sì tún mọ odi Adágún Ṣela ti ọgbà ọba títí kan àtẹ̀gùn tí ó wá láti ìlú Dafidi.

Ka pipe ipin Nehemaya 3

Wo Nehemaya 3:15 ni o tọ