Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemaya 3:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Hanuni ati àwọn tí ń gbé Sanoa tún Ẹnubodè Àfonífojì ṣe, wọ́n tún un kọ́, wọ́n sì ṣe àwọn ìlẹ̀kùn rẹ̀. Wọ́n ṣe àwọn ọ̀pá ìdábùú rẹ̀, wọ́n sì tún odi rẹ̀ kọ́ ní ìwọ̀n ẹgbẹrun igbọnwọ (mita 450), sí Ẹnubodè Ààtàn.

Ka pipe ipin Nehemaya 3

Wo Nehemaya 3:13 ni o tọ