Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemaya 2:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo fún ọba lésì pé, “Bí ó bá tẹ́ kabiyesi lọ́rùn bẹ́ẹ̀, kí kabiyesi kọ̀wé lé mi lọ́wọ́ kí n lọ fún àwọn gomina ìgbèríko òdìkejì odò, kí wọ́n lè jẹ́ kí n rékọjá lọ sí Juda,

Ka pipe ipin Nehemaya 2

Wo Nehemaya 2:7 ni o tọ