Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemaya 2:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀rù bà mí pupọ.Mo bá dá ọba lóhùn pé, “Kí ẹ̀mí ọba gùn! Báwo ni ojú mi kò ṣe ní fàro, nígbà tí ìlú tí ibojì àwọn baba mi wà, ti di ahoro, tí iná sì ti jó àwọn ẹnubodè rẹ̀?”

Ka pipe ipin Nehemaya 2

Wo Nehemaya 2:3 ni o tọ