Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemaya 13:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà mo wẹ̀ wọ́n mọ́ ninu gbogbo nǹkan àjèjì, mo sì fi ìdí iṣẹ́ wọn múlẹ̀ gẹ́gẹ́ bí alufaa ati ọmọ Lefi. Olukuluku sì ní iṣẹ́ tí ó ń ṣe,

Ka pipe ipin Nehemaya 13

Wo Nehemaya 13:30 ni o tọ