Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemaya 13:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo kìlọ̀ fún àwọn ọmọ Lefi pé kí wọ́n ya ara wọn sí mímọ́, kí wọ́n wá láti ṣọ́ àwọn ẹnubodè, kí wọn lè pa ọjọ́ ìsinmi mọ́.Ranti eléyìí fún rere mi, Ọlọrun mi, kí o sì dá mi sí gẹ́gẹ́ bí ìfẹ́ ńlá rẹ tí kì í yẹ̀.

Ka pipe ipin Nehemaya 13

Wo Nehemaya 13:22 ni o tọ