Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemaya 13:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo tún rí i wí pé wọn kò fún àwọn ọmọ Lefi ní ẹ̀tọ́ wọn, tóbẹ́ẹ̀ tí àwọn ọmọ Lefi ati àwọn akọrin, tí wọn ń ṣe iṣẹ́ náà fi sá lọ sí oko wọn.

Ka pipe ipin Nehemaya 13

Wo Nehemaya 13:10 ni o tọ