Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemaya 12:47 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà ayé Serubabeli ati Nehemaya, gbogbo àwọn ọmọ Israẹli a máa fún àwọn akọrin ati àwọn olùṣọ́ ẹnu ọ̀nà ní ẹ̀tọ́ wọn ojoojumọ, wọn a máa ya ìpín àwọn ọmọ Lefi náà sọ́tọ̀, àwọn ọmọ Lefi náà a sì máa ya ìpín àwọn ọmọ Aaroni sọ́tọ̀.

Ka pipe ipin Nehemaya 12

Wo Nehemaya 12:47 ni o tọ