Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemaya 12:43 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n ṣe ìrúbọ pataki ní ọjọ́ náà, wọ́n sì yọ̀, nítorí Ọlọrun jẹ́ kí wọ́n yọ ayọ̀ ńlá, àwọn obinrin wọn, ati àwọn ọmọ wọn náà yọ̀ pẹlu. Àwọn tí wọ́n wà lọ́nà jíjìn réré sì gbúròó igbe ayọ̀ ní Jerusalẹmu.

Ka pipe ipin Nehemaya 12

Wo Nehemaya 12:43 ni o tọ