Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemaya 12:37 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní Ẹnubodè Orísun, wọ́n gòkè lọ tààrà sí ibi àtẹ̀gùn ìlú Dafidi, ní igun odi ìlú, ní òkè ààfin Dafidi, títí lọ dé Ẹnubodè Omi ní apá ìlà oòrùn ìlú.

Ka pipe ipin Nehemaya 12

Wo Nehemaya 12:37 ni o tọ