Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemaya 12:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Joiakimu jẹ́ olórí alufaa, àwọn alufaa wọnyi ní olórí baálé ní ìdílé tí a dárúkọ wọnyi:Meraya ni baálé ní ìdílé Seraaya,Hananaya ni baálé ní ìdílé Jeremaya,

Ka pipe ipin Nehemaya 12

Wo Nehemaya 12:12 ni o tọ