Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemaya 10:38 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn alufaa, ọmọ Aaroni yóo wà pẹlu àwọn ọmọ Lefi nígbà tí àwọn ọmọ Lefi bá ń gba ìdámẹ́wàá, àwọn ọmọ Lefi yóo yọ ìdámẹ́wàá gbogbo ìdámẹ́wàá tí wọ́n bá gbà lọ sí ilé Ọlọrun wa. Wọn óo kó o sinu gbọ̀ngàn ninu ilé ìpa-nǹkan-mọ́-sí.

Ka pipe ipin Nehemaya 10

Wo Nehemaya 10:38 ni o tọ