Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemaya 10:1-8 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Àwọn tí wọ́n fi ọwọ́ sí ìwé náà tí wọ́n sì fi èdìdì dì í nìwọ̀nyí: Nehemaya, gomina, ọmọ Hakalaya, ati Sedekaya.

2. Lẹ́yìn náà, àwọn ọmọ alufaa wọnyi: Seraya, Asaraya, ati Jeremaya,

3. Paṣuri, Amaraya, ati Malikija,

4. Hatuṣi, Ṣebanaya, ati Maluki,

5. Harimu, Meremoti, ati Ọbadaya,

6. Daniẹli, Ginetoni, ati Baruku,

7. Meṣulamu, Abija, ati Mijamini,

8. Maasaya, Biligai, Ṣemaaya. Àwọn ni alufaa.

Ka pipe ipin Nehemaya 10