Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemaya 10:1-15 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Àwọn tí wọ́n fi ọwọ́ sí ìwé náà tí wọ́n sì fi èdìdì dì í nìwọ̀nyí: Nehemaya, gomina, ọmọ Hakalaya, ati Sedekaya.

2. Lẹ́yìn náà, àwọn ọmọ alufaa wọnyi: Seraya, Asaraya, ati Jeremaya,

3. Paṣuri, Amaraya, ati Malikija,

4. Hatuṣi, Ṣebanaya, ati Maluki,

5. Harimu, Meremoti, ati Ọbadaya,

6. Daniẹli, Ginetoni, ati Baruku,

7. Meṣulamu, Abija, ati Mijamini,

8. Maasaya, Biligai, Ṣemaaya. Àwọn ni alufaa.

9. Lẹ́yìn náà àwọn ọmọ Lefi wọnyi: Jeṣua ọmọ Asanaya, Binui ọ̀kan ninu àwọn ọmọ Henadadi, ati Kadimieli,

10. ati àwọn arakunrin wọn: Ṣebanaya ati Hodaya, Kelita, Pelaaya, ati Hanani,

11. Mika, Rehobu, ati Haṣabaya,

12. Sakuri, Ṣerebaya, ati Ṣebanaya,

13. Hodaya, Bani, ati Beninu.

14. Àwọn ìjòyè wọn tí wọ́n fọwọ́ sí ìwé náà ni: Paroṣi, Pahati Moabu, Elamu, Satu, ati Bani,

15. Bunni, Asigadi, ati Bebai,

Ka pipe ipin Nehemaya 10