Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemaya 1:5 BIBELI MIMỌ (BM)

“OLUWA Ọlọrun ọ̀run, Ọlọrun tí ó tóbi tí ó sì lẹ́rù, Ọlọrun tíí máa pa majẹmu ati ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ mọ́ pẹlu àwọn tí wọ́n bá nífẹ̀ẹ́ rẹ̀ tí wọ́n sì ń pa òfin rẹ̀ mọ́,

Ka pipe ipin Nehemaya 1

Wo Nehemaya 1:5 ni o tọ