Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemaya 1:10-11 BIBELI MIMỌ (BM)

10. “Iranṣẹ rẹ ni wọ́n, eniyan rẹ sì ni wọ́n, àwọn tí o ti fi ipá ati agbára ọwọ́ rẹ rà pada.

11. OLUWA, tẹ́tí sí adura èmi iranṣẹ rẹ, tí mo bẹ̀rù orúkọ rẹ, kí o sì jẹ́ kí n ṣe àṣeyọrí lónìí, kí n sì rí ojurere ọba.”Èmi ni agbọ́tí ọba ní àkókò náà.

Ka pipe ipin Nehemaya 1