Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nahumu 3:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ẹlẹ́ṣin ti múra ìjàpẹlu idà ati ọ̀kọ̀ tí ń kọ mànà.Ọpọlọpọ ni wọ́n ti pa sílẹ̀,òkítì òkú kúnlẹ̀ lọ kítikìti;òkú sùn lọ bẹẹrẹ láìníye,àwọn eniyan sì ń kọlu àwọn òkúbí wọn tí ń lọ!

Ka pipe ipin Nahumu 3

Wo Nahumu 3:3 ni o tọ