Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mika 7:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Ta ló dàbí rẹ, Ọlọrun, tí ó ń dárí ẹ̀ṣẹ̀ ji eniyan, tí ó sì ń fojú fo ẹ̀ṣẹ̀ àwọn eniyan ìní rẹ̀ yòókù, ibinu rẹ kì í wà títí lae, nítorí pé a máa dùn mọ́ ọ láti fi ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ hàn.

Ka pipe ipin Mika 7

Wo Mika 7:18 ni o tọ