Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mika 6:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ óo jẹun, ṣugbọn ẹ kò ní yó, ebi yóo sì túbọ̀ máa pa yín, ẹ óo kó ọrọ̀ jọ, ṣugbọn kò ní dúró lọ́wọ́ yín, ogun ni yóo sì kó ohun tí ẹ kó jọ lọ.

Ka pipe ipin Mika 6

Wo Mika 6:14 ni o tọ