Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mika 1:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọ̀rọ̀ tí OLUWA sọ fún Mika, ará Moreṣeti nípa Jerusalẹmu ati Samaria nìyí, ní àkókò ìjọba Jotamu, ati ti Ahasi ati ti Hesekaya, àwọn ọba Juda.

Ka pipe ipin Mika 1

Wo Mika 1:1 ni o tọ