Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Malaki 3:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn, ta ló lè farada ohun tí yóo ṣẹlẹ̀ ní ọjọ́ tí ó bá dé? Àwọn wo ni wọn yóo lè dúró ní ọjọ́ tí ó bá yọ?Nítorí pé ó dàbí iná alágbẹ̀dẹ tí ń yọ́ irin, ati bí ọṣẹ alágbàfọ̀ tí ń fọ nǹkan mọ́.

Ka pipe ipin Malaki 3

Wo Malaki 3:2 ni o tọ