Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Malaki 2:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó fi ẹ̀kọ́ òtítọ́ kọ́ni, kìí sọ̀rọ̀ àìtọ́. Ó bá mi rìn ní alaafia ati ìdúróṣinṣin, ó sì yí ọkàn ọpọlọpọ eniyan pada kúrò ninu ẹ̀ṣẹ̀.

Ka pipe ipin Malaki 2

Wo Malaki 2:6 ni o tọ