Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Malaki 1:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìbá ti dára tó kí ẹnìkan ninu yín ti ìlẹ̀kùn tẹmpili pa, kí ẹ má baà máa wá tanná mọ́, kí ẹ máa rú ẹbọ asán lórí pẹpẹ mi! Inú mi kò dùn si yín, n kò sì ní gba ọrẹ tí ẹ mú wá.

Ka pipe ipin Malaki 1

Wo Malaki 1:10 ni o tọ