Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 9:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Sì sọ fún àwọn eniyan Israẹli pé, ‘Ẹ mú òbúkọ kan fún ẹbọ ìmúkúrò ẹ̀ṣẹ̀, ati ọmọ mààlúù kan ati ọ̀dọ́ aguntan kan fún ẹbọ sísun, kí àwọn mejeeji jẹ́ ọlọ́dún kọ̀ọ̀kan, wọn kò sì gbọdọ̀ ní àbààwọ́n.

Ka pipe ipin Lefitiku 9

Wo Lefitiku 9:3 ni o tọ