Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 7:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ẹnikẹ́ni bá fọwọ́ kan ohun àìmọ́ kan, ìbáà ṣe ohun àìmọ́ ti eniyan, tabi ti ẹranko tabi ohun ìríra kan, lẹ́yìn náà tí ó wá jẹ ninu ẹran tí a fi rú ẹbọ alaafia sí OLUWA, a óo yọ ẹni náà kúrò lára àwọn eniyan Ọlọrun.”

Ka pipe ipin Lefitiku 7

Wo Lefitiku 7:21 ni o tọ