Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 6:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹni tí wọ́n bá yàn sí ipò olórí alufaa lẹ́yìn Aaroni ninu àwọn ọmọ rẹ̀ ni yóo máa rú ẹbọ yìí sí OLUWA gẹ́gẹ́ bí ìlànà títí lae, gbogbo ìyẹ̀fun náà ni yóo fi rú ẹbọ sísun.

Ka pipe ipin Lefitiku 6

Wo Lefitiku 6:22 ni o tọ